Tira iferan obinrin

understand you. opinion you commit..

Tira iferan obinrin

Imule to daju Eye kowe dudu kan isu esuru pupa ati atare kan ,ao fi kowe dudu tele ape ao ko esuru lelori ao fi atare si o di jijo papo Lilo re; aofi oti Lo laro aofi epo pupa lo lale. Tested and confirmed, aje funwa o.

Edan Aje:- ewe odunkun,ewe awede, ewe sekinimidin, ewe ESO,ewe sawerepepe, mariwo Ope, tete abalaye, efo gure, so rate edan meji, ako ati abo, so pa Gbogbo ewe yen po ninu ike funfun NLA kan ao wa da omi agbon topo le lori Pelu oti dry gin, ao wa ko edan mejeji si, ao ma fi omi yi we fun ojo meta, ni ojoketa tati we tan a ko edan na sori nkan kogbodo kanle ao wa fi eyele funfun Pelu eyetu bo awon edan na ao wa ko sinu Awo fun, ao ma fi ekuru se Sara fun edan yi ao si ma fi dry gin si ni gbakugba taba feran nise Pelu Adura, Edan Alaje ni.

Ekaro Gbogbo ile emi Omo yin ni Woli Opa mo npada bo. Fun ita tabi igbona, E lo wa ewe rinrin ki e lo loju olo, e pin so ona meji. On a keji,efi epo pupa die si, kie fi pa onitohun lara. Ki ama se fi pa atelewo pelu atelese.

Android steps api

Logo Olorun ara onitohun yio bale. Mosi tun she ebu oshole yi. A o wa eso bomubomu a o la tenre a oki N, tuntun ti a ka ti aworan eniyan inue koju si ita, pelu odidi atare kan bo inue ti koni han sita rara, a o wa jo, a o lo kuna, a o fi oti loo ni aro kutukuti ki ato ba enikankan soro, ni ihoho omo luabi.

tira iferan obinrin

A o se adura ohun ti a fe si kato loo. Eiye AWOKO, atare, sekere aloku ti koba si ileke larare mo, ao ha arare ao wa gun po mo atare naa ao wa yo okan eye AWOKO naa ao tun gun po mon oun ti ati gun naa yio Dabi agunmu ao ma fi oti oyinbo loo fun ojo mesan sugbon ti aba fe losi ibi Orin ao tun loo lo enina ma korin tio kori yio korin akogbayi, awon aye o siwona fun oooo.

Aseje owo Ewe abamoda 3, pelu ata ijosi 9, a lo lori olo and fi po eyin agric 3, a wa da sinu nilonu ti won fi di sugar ao fi iyo die si, ao se jina, a o wa se adura si ki a to je. Odaju Ose Get ewe iyalode funfun ati pupa 3 ,3 ti ko luju, a o lo pelu koun bilala die kan, a o wa lo lori olo a o wa fi ose ko, ti o ba di ni ale ao wa eki elewe a wa ge si meji, a o mu ti ori yen a o fi epo po ninu abo laifi omi si, a wa fi pa gbogbo ara lati ori, a o wa we ose na pelu kankan tutun.

Ao wa losun lale ojo na lai jade sita mon. Ogun iferan todaju Ota inun iroko,epo egusi ti obinrin se funra re,ao lo papo ao da sinu bintle ao ma fi para lo ba obinrin naa.

Jpg to gcode

Ogun iferan. September 05, BY ME AGBARA OMI Edan Aje:- ewe odunkun,ewe awede, ewe sekinimidin, ewe ESO,ewe sawerepepe, mariwo Ope, tete abalaye, efo gure, so rate edan meji, ako ati abo, so pa Gbogbo ewe yen po ninu ike funfun NLA kan ao wa da omi agbon topo le lori Pelu oti dry gin, ao wa ko edan mejeji si, ao ma fi omi yi we fun ojo meta, ni ojoketa tati we tan a ko edan na sori nkan kogbodo kanle ao wa fi eyele funfun Pelu eyetu bo awon edan na ao wa ko sinu Awo fun, ao ma fi ekuru se Sara fun edan yi ao si ma fi dry gin si ni gbakugba taba feran nise Pelu Adura, Edan Alaje ni.

Ao wa losun lale ojo na lai jade sita mon Ogun iferan todaju Ota inun iroko,epo egusi ti obinrin se funra re,ao lo papo ao da sinu bintle ao ma fi para lo ba obinrin naa.

Post a Comment. Popular posts from this blog Ogun asiri bibo September 05, Ako Alangba, Eyin adie kan aofitele ape aoko, Ewe sasamura lelori a o se lagbo, ti obajina aoko ewe na sile aoduro lelori aowe agbo naa, aowaje Eyin adie yen nibe, atisegun ibalopo oju orun ati alakala niyen.

Read more. Aseje owo Pepper soup 4 money 50, upwards Ewe lapalapa funfun Jatropha curcas mejila aoko mefa tele aoko eyin agric 3 le ao wafi mefa yoku bo ao se jina laisi omin ao daniyan owo si niti bukata tanfe ao waje.

Koda ogbeE kale Gbogbo ile, a ku ipale mo a ba wa layo. Ewe owu akese, ewe ajeobale, ewe laali, aogun po mo ose, ao ma fiwe ni aroo A o lo epo obo ti yio kuna, a o po mo ose, a o fi omi igbi….Moki gbogbo ile lapapo mo fe ki gbogbo ile je anfaani ise yi walahi iwo ti oba ri lo gbiyanju re wo ki owa funmi labo lori re Ise iferan gbogbo aye ni toripe mori awon opolopo eeyan ninu group tiwon sope awon nidi iferan idi niyen ti mose ni kin ba gbogbo ile post ise iferan gbogbo aye yi Ise naa lolo bayi pe Walahi mafi ojudi lo gbiyanju re ki o mo ooto ibe Egbo lapalapa pupa ati funfun ati epo obo ao wa gunpo mo ose dudu ao maa we ose yi ni ale ki atosun and ti aba we o Ise yi na daju debi wipe oruko ti a fun ifa na ni "ese kan ola".

Walahi, en Ise na niyi. Ori ewure tutu kan, ako fun okunrin, abo fun obinrin, ewe sawerepepe, ewe aje, ewe ela, ewe ogo, ewe ire, ewe akisan, ata ijosi topo die, isasun aseje die.

SISE RE- A O lo awon eroja yen ni ototo, a o ma da sinu isasun, bi aba se nlo, a o ge ori ewure si mesan fun okunrin, meje fun obinrin, a o ko sinu isasun na, a o se lepo niyo, ti o ba jina, a o fi iyere osun te ifa ogundabede sinu paper funfun kan, a o pe ofore si, a o dasi aseje na leyin ofore, a o ko aseje na je. Ori osuka ni aseje na mawa. Ojo monday ni aseje yi dara ju lati je, tori ki owo wa bale te ire aje nla. Ogun eyonu ashinna kia kia. Ogede omini meter ati ewe bomubomu mesan fun okunrin meje fun obinrin ao po lo se ao ma fi we laro ati ni ale.

Ti yan ba lo ise yin obinrin ma po gan to ba je obinrin lo lo ise yin okunrin ma po fun gan. Aojo papo, aolo yiokunna daada. Aomalo pelu peak milk Kokan ni ojo Kokan fun ojo meje Lona basi fun eeeee Aye oni dinna mowa ooo. Mafi ojudi pe okere loogun sugbon AGBA ise ni ninu awon ise tonje Ilosiwaju yin ni iwuri temi na Akiyesi:- fun enikan soso nio Ire oooooo. Aseje eyonu kan niyi ti ko nayan lowo rara tosi daju gan Eso tannapowo ao ja niwonba ti yio po pelu ata ijosin tabi iyere ao wa fise eja toba wuwa je lepo niyo Jowo mifi olorun beyin ema bere ibere ti koni itumo lowo mi oooo Gbogbo wa pata ni ao ri tiwa se.

Sa flip up sights

Jump to. Sections of this page. Accessibility help. Email or phone Password Forgotten account? Sign Up. Asiri tira awon agbalagba Public group.Am very jovial and caring person but highly disciplined. Email: tomiwag gmail. Ole koni wo ibi ile ti aba fiko laelae. Ofore :- Ododun ni sapo nwu ewe, ososo ni peregun nse ofo iyare, ako eyele kini isimi, gbogbo eni toba nse oun buburu simi koma ni isimi.

Eku ise sir, awon ti o ni aiye a je ko ma ju yin se o, ashe. E jowo baba. Ogun wo ni alefigba owo ti awon eniyan je wa. E se pupo.

E se pupo Owo ta ni e ti fe gba unkan na. Ejowo baba, omo ile iwe poly ni mi, mo nilo ogun isoye todaju tabi ohun ti mo le lo ti ma fi ni distinction in idanwo tin mon mura lati ko. Owo awon ore mi ni sugbon won ti wa ya alaimore. Ejowo baba. E o da mi loun mo. Eyonu eleiye Eyin adiye ibile kan,iyo die,aa se eyin naa ,aaa da iyo na sinu abo pelebe white plate aa o mu eyin naa sori iyo,aa o gbee sinu orun,aa o gbe Wole pada ni deedee agogo mejila osan 12pm aa o bora sinu ihoho, aa o Bo eyin adiye naa,aa o fi kan iyo die,aa so si enu lodidi.

OFO re: ogundabede awo olokun loni ki omoraiye maa foju ire wo mi loni, afema ni obinrin nfe a,a mama ni eniyan Moro ,tomode tagba lo mo Afin loja,a kii tori obo ka yo be,gbogbo eniti o dami mo ati eniti ko dami mo ki e maa yonu simi. Ejowo kin to le gba yin laye lati ma fi unkan si ori ikani yi e pe mi lori ero e bara eni soro. Ao maa fiwe ori de orun. NB: ako gbudo fi ose yi we gbogbo arawa Ewo nio. Asina Fun eniti Ona dima ti korise se ti koni owo lowo Ao ra koko isasun tuntun opolopo omin agban ao da omi na sinu koko isasun ao gbe kana ao lo epo obo kuna ao dasi ao tunwa da ose dudu si ao wa ma ro bi igbati anro amala toba ti darapo dada ao so kale kotutu ao ma buwe ijo keji loti bere si ni gba ise ati owo odaju ti aba wa lo gbogbo oseyi tan ona yio ti si funo dada owa gbe koko na lo si egbe ori atan owa so wipe ota to ndina mami tio lepe mi laburu ona tiedi motisi o tebako ti ekoba jawo month foyin male lonio eo tun gberi ma ao wa fo koko na male ao ma losi ile tara lai boju weyin Iba fun awan agbagba moju ba omoyin ni mi efi oju ire womi o.

Agbo idoti Abe to nfa isunki nkan omo okunrin ati idakole Bara totobi dada kan, ope oyinbo pineapple kan epa ikun ati kanun gidi die Ao fo bara na yio ma dada ao ge kekeke ao ko sinu oru agbo tabi koko ao tun ge pineapple na kekeke ao kosi ao ko epa ikun lelori ao ge oun na kekeke ko po die ao ge kanun gidi ni wanba si ao wa bu omi toma dada si ao de ao wa se ti yio jina dada apere toba ti jina omi agboyi yio duduwa lekannan oti jina nu ni ao so kale toba tutu dada ao ma mun ni tonbila kokan lojojuma leyin ose meji tanti lo agboyi ao lore ra ogede agbagba dudu to gun dada ao bo epore ao so sinu koko tolegba akogbodo ge ao bu omisi pelu oyin gidi sibi mesan ao se to ba jina ao je gbogbore lekannan ise ya NB ti oko bati ni iyawo agboyen nikan ni kose mase ti ogede o!

NB agboyi yio ma kowa ninu yio ma lowa ninu emase beru idoti yen lonko ni abewa ti eyin gan base igbanse eru yio bayin pelu nkan idoti tama ya jade, ao si riwipe nkan omo kunrin wa jipepe yiowa bi ose ye kowa yio si ma sise daradara ti yio si yojade pada fun eniti tie ti sunki Adua wa yio gba lase oba odumare Mojuba awon agbagba. OGUN IFERAN Gbogbo nkan lalelofun Ewe omisimisi gogoro ati pelebe, gilasi tiwan nfi wo oju dada, koro sugar meta ao lo kuna dada ao teni eji ogbe ao pe ohunre si ao da sinu oyin ao mala Eleri ikan 3x Aba orisa 3x Amunidele ire 3x Arile rere yasi woni lewu ola 3x, Awon mererin niwon da ifa fun orunmila nigbati ifa nlo ba olokun sore 3x won ni olokun ma binu siyan ni 3x orunmila ni olokun koni binu si ohun, won ni ibinu omo araye nko, orunmila ni koni binu si omo araye, oni nitoripe oba ilu kibinu oba ilu, oba osin kibinu oba osin, Oba Ajalaye kibinu Oba Ajalawarun, Oba ajalawarun kibinu oba olomerenmere, Oni bi omode bawo digi arerin bi agbalagba bawo digi arerin, nitori adun duntan niti ewe omisimisi ndun kan araWon, Adun denu ni sugar ndun, omode ki fi oyin senu ki opose, Agbalagba kifi oyin senu ki opose, EJIOGBE gbe ife mi si okan Horlahcoded : mo fe ogun "egbe" to daju Se mo le be ree oun ti e fe fi se.

Horlahcoded : fun idabobo Send me a blank message to belatoxx gmail. All rights reserved. See How To Advertise.Plss sir more of dis nd the 1 for protection nd healing people nd i wud lyk to no more abt eye aye. Ewe ategbo. Almighty god we continued to bless ur work ,I need awo igba arun that can cure any type of sickness. I really appreciate your effort may God eledumare continued to shower you blessing. This is wonderful, may God bless more with this. What u gave free to us will be charge with a lot money in somewhere else.

Pls, I hv a kid and almost 4yrs, he can't sit or walk up till now, he can't also talk. If there is anything you could help on this, I will appreciate. E jowo e fi oogun adult bedwetting to daju se aanu. Eni Sise O Lase Eledua. Ajinde ara o maa je o.

Ejowo sir,ti mo ba ti sun ti mo ba taji lati oju orun,mi o ki n le so oro,mi o ki n le da aragbe lati dide,o ma n da bi eni wipe,won de mi ni okun monle. Edakun baba kini ona abayo?

Ajinde ara o ma je o. Edakun ejowo kini ona abayo? Ti mo ba taji lati oju orun,mi o ki n tete ni anfaani lati soro jade,ti mo ba fe so oro mi o ki n ni anfaani lati so oro,o ma n da bi eni wipe,won de mi ni okun monle lati ma le kuro ni oju kan.

Edakun e sanu mi o. Ori Inaki kan 2. Ori Ekun kan 3. Odindi Eiye Okin kan 4. Ori Ere Nla kan ati Ase re 5. Opolopo Ewe Orijin 6. Odindi Ataare 16 Ao jo gbogbo re po Ao da opolopo ewe Orijin yen le lori ao wa jo dadaa.

tira iferan obinrin

Ao lo kunna. Eni ti o ni ogun yi ko gbudo je ninu Adiye yen Ao ma fi Oti Schinap lo Ogun yi ni dede ago am oru ni ojo meta meta Ao gbudo ba Obinrin lo po larin Ojo Meta lehin igbati aba lo ogun yen tan Obinrin ti o se unkan osu ko gbudo fi owo kan ose yen oo. Orogbo, obi gbanja, etu ibon, ako okuta, esuru funfun, ege ti a nfi ngun iyan je, ogede agbagba dudu, agbado, iyere ao fi sugar die si ao gun po ao maa fi foko tutu mu.Adie asa kan, Ewe mafowokanmomi tutu, Odindin atare nla kan, Sise re: Ao rora ge idi adie na roboto, ao ko ifun ati Edo re jade lati idi, Wednesday, January 6, Ao ja ewe kan lori igi ibepe ti o so dada, ao bu die ninu iyepe oja ti o kun dada, erupe orita meta, ati erupe akitan ti o gba ore, ao gun po ao fi oyin gidi po, pelu ose ao fi omo ayo kan gun lori, ao ko sinu ike funfun ao ma fi we o daju.

AKOYA ABENU GONGO TOGBONA: ewe ailu, ewe kilofefimise, ewe mafowokan omo mi, ewe atikaparare, ewe gbegbe, ewe tete, awo ekun die, epo obo, odidin atare kan, ao lo wa ikaraun ibin to tobi ninu igbo, ibi ti won ba ge imo ewe ope eyin si, ni eti le saba ri ikaraun ibin, tabi ki e so fun awon elewe o mo ki won ba yin wa, amo ko je ti korofo ikaraun ibin tinu igbo gan gan, ao ko gbogbo awon eroja yi sii ikaraun ibin na. Ao fi aso pupa bo ooo loju, a o fi owu dudu ati funfun di ni iko bere ti ara re ko ni han sita, owu iranso lao lo ao lo ri mole si orita meta ni oru night fun ojo meta, to ba ti di ojo keta, ao lo wu kuro nibe ni ale, ao jo lai tu, ao lo kunnaa, ao da si meta, afi idan kan: sin gbere yii abadi wa ka, ao wa sin bere ejiogbe si center lona meta si isale re.

Ao fi idakeji: ao ko lose dudu, ao ko sinu iba funfun, after 7days, lao fi we ni ago kan osan lekan soso. AO FI IDA KETA: ao da sinu awo funfun ao we ni tira pelu owu dudu ati pupa, ao fi aso pupa ran ni olounde ao wa fi owu ibile dudu ati funfun we round ti olounde yen ko ni han jade, ao ma wo si ibadi, after 7days ti aba ti fi ose yen we ni ao ma wo siidi.

Ao si ni ma fi olounde yen we, ao ma bo remove ti aba fe we. Maran: ogun yii deenaa kiko aisan ni pa ibasun tabi ti won ba le magun fun obinrin, ti aba ba ni ajosepo, tabi ti won ba fi ogun gbawa, ko si nkan ti yo se wa aforan: ojo ti ijanba ba fe sele si wa, o le je ija n ba MOTO, tabi OLE, or OGUN war ti nkan ba sele si gbo gbo won, ko si ikan ti yio o sele si wa, lai fi arapa.

Finite automata

Sugbon eto itoju to muna doko wa fun ohun te beere sugbon kii se inkan ta le fi sori afefe. Orisi eto meta wa ti a ma n se ni sise n tele fun inkan omokunrin to ba kere tabi ko sise daada. E kan si mi lori e-mail Biiii eloooo niii. Ao ma fi foko mu.

tira iferan obinrin

Ao ba oogun na ro ejo ohun ti a fe ko sele ninu Ile naa. Newer Post Older Post Home. Subscribe to: Post Comments Atom.To ba se ise yi wa ri wipe oda bi wipe osan gbese ara re yo fuye inu re yo si ma dun aje wipe ide tija niyen ELEYI NI ATUDE OWO AYE LARA Odaju gan ni ona yo si la gidi egbo tude die,die,isawuru metato ni omo ninu ao gun egbo tude po mo isawuru kan aogun mo ose iwe ekan pere ao se ekeji na be ao se eketa na be ao wa fi eyokan we ni owuro,ikan ni osan,ikan ni ale walah oori bi arare yo se ri nijo keji walahi.

Adie asa kan, Ewe mafowokanmomi tutu, Odindin atare nla kan, Sise re: Ao rora ge idi adie na roboto, ao ko ifun ati Edo re jade lati idi, Wednesday, January 6, OFORE: Siju womi, abifa gbuuru, siju womi la npe ifa, abifa gburu la npe esu odara, itun loni ki e fi enu rere tun mi se, ifa loni ki won fenu rere fami mora, ogbo loni ki won mu temi gbo,oro mi ka sai yo won ninu gerere, bi epo bafoju kan oorun ayo gerere, bi adi ba foju kan oorun ayo gererebi ori ba foju kan oorun ayo gerere bi awo ba fi oju kanna woranworan agun, bi oloko ba joko bi olobo ba debe a fi aye gba, Orisa sanu agbe o se aso re laro, orisa sanu aluko ose aso re losun, Ao se iwure fun ohun ti a fe.

Pelu Ase awon to laye, bi Ejo oka o ba ku, iru idi e kii fi sile lo.

Hoton duri da bura

OFO RE; Ope Eluju lo ko igba, lo ko Aake; difa fun Alaketu ti Otalele'gbesan eniyan nji ko otalele'gbesan edi ti, Ifa ni egun kegun ko tie lee mu mi, egun iyan kii modo, egun isu kii mobe, egun ina kii mu aaro, Ifa ni ariwo mi ti omo araye n pa ko ni le se buruku fun mi, ariwo ega susu kii pa Odan, Ifa ni ariwo roro ko ni se Oja ni nkan, Ifa ni temi ni tio ma se, ti ng o ma ni ire gbogbo, takese ni se lawujo owu, tijimere ni se lawujo gbogbo eranko.

O da ko Adebori ti ise yeye adan, t'o b'aro lomo sori igi. Oun ni Afomo! Beeni igi tio ba si fi ti afomo se, afomo naa nii pa!.

Orunmila ni nje oro yi di kaka-ngbasa, mo ni o di onigikigi. Ifa ni "Igikigi kii maa ba Asunrin fori gbori. Eyin adie ki i dariso okuta, igbin kii dariso iyo. Ina ki i dariso omi. Owo koko l'a fii wo igi. Owo orisa la fi i wo imole.

Kujore Oluwatomisin ma di eni owo, E j'olowo o lo o. Afin ni Oluwatomisin, ki i se eni aa gba loju. Aro ni Oluwatomisin, ki i s'eni aa na. Abuke Orisa ni mi nki i seni aa di ni kanin-kanin.

OOGUN IFE (the sequel of IWAKIWA)

Ao lo awon meteeta ni otootoao ko po epo obo mose, ao wipe pe eyin aiye o, ao jewo Isele ti o sele si won bi a se n po mose, mo nbeyin lowe, mo si fe ki e ba mi se. Ori ako okuta ni ao ti we. Awo ewure dudu, Irun abe, Ewe amunimuye, Odidi atare kan, Ekanna owo 10 ati ese 10Iru ipenpeju eniyen die, Irun ori die. Ao jo gbogbo re po ao ma fi sinu ounje tabi obe die fun eni naa, ti o ba ti je yio nife re. Odaju Iba eyin agbagba, aye mujuba. Unknown February 5, at AM. Baba ogbagba April 25, at AM.

Unknown July 12, at AM. Newer Post Older Post Home. Subscribe to: Post Comments Atom.Coming soon on 1st JUNE Ori akuko adie togbo dada ao fi sinu agbada ijo nkan ao ko ewe akoko bomole ao fi odidi atare kan si ao jo ao lo kuna ao da oyin si ao ma fi ika arin ropo ao ma la isoye yi dara otun sise fun awon omo keke tiwan lo ile iwe ao so wipe ki wan ki ika arin bo kiwan la, inu roba ti owo hand lewo la dasi ti ao ti mala OGUN TUDE TOODAJU. Egbo lapa funfun ti ori akitan,Egbo lapa pupa ti won fi se ogba School ile iwe ,Aso funfun opa kan,opolo aye kan.

Egbo lapalapa eyikeyii.

tira iferan obinrin

Ao ge kekeke si inu ike kan. Ao wa Alangba eyokan ao jo papo pelu odidi Atare kan ao lokuna dada. Ao wa da sinu egbo take kekeke yen Thehomeofsuccess gmail. The qualities of herbs are recognized for both spiritual and physical well-being. It is believed that the force that drives the universe, known as ASE, is in part locked up plant life awaiting use by those who have the knowledge to unlock it.

The rites indigenous to the faith of the Yoruba could not exist without the herbs provided by Osanyin and the ASE within them. It is by his invocation and permission that the primary rituals of consecration are realized. But his older brother Orunmila wanted Osanyin to feel worth.

THE HOME OF SUCCESS, HEALING AND TRADITIONAL MEDICINE

Orunmila arranged to leave Osanyin on the farm early in the morning with the instruction to pull weeds from between the rows of crops. When Orunmila returned in the evening, he found Osanyin in the middle of the field weeping, without a single weed pulled.

Orunmila asked his brother why he was weeping and why he had not completed his task. Orunmila was taken by surprise that his brother had such deep knowledge. Osanyin gifted each deity with the herbs and sacred knowledge most compatible with their individual spirits. When we view plants, most of us see only the outer green; it takes a person deprived of other senses and abilities to see the inherent energy within. Osanyin, although lame, is powerful just the same.

Through the deprivation of certain functions, he has been gifted with one more potent. His priests are distinctive, a cult not given to trance, as are the other cults.

These priests speak through a direct link to their tutelary ORISHA as if their tongues were being rattled by a divine ventriloquism. The deity has a strong association with birds, especially owls. This is not lost on Osanyin, whose knowledge is deeply esoteric.

The iron staff by which an Osanyin priest is known often is shaped like plant branches shooting out of the ground, surmounted by a lone bird with wings spread in flight. Osanyin is typically seen as a loner who wanders the fields.

Osanyin is to himself, picking his herbs, and communing with nature. His messages and nature are enigmatic, like his voice. As we recognize, without Osanyin the rites of the Yoruba could not take place. This is true whether the priest is in Yoruba-land or in the Diaspora. All rites must include herbs and plants of nature. Adherents also classify herbs as male and female, as well as herbs of day and herbs of night and by those that incite or calm. Collection of herbs is usually done in the forest or a field.

Offerings of money, kola nuts, and gin are usually made. So sacred are plants to the Yoruba and their spiritual descendants that many of the herbs have their own sacred songs. In the making of OMI ERO, for instance, the priest will sing these ancient songs over the herbs as they are being used. With these sounds the priests become imbued with the ASE in their own voices, as well as serving to remind the herb of the qualities that they bring to the sacred rites. Each is known to Osanyin and perhaps, after calling his name and praying to him, you might hear his birdlike voice gently instructing on their use.

Ori Inaki kan 2.


Zolotilar

thoughts on “Tira iferan obinrin

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Back to top